ÀWỌN ADÁJỌ́ 5:2-3
ÀWỌN ADÁJỌ́ 5:2-3 YCE
Ẹ fi ìyìn fún OLUWA, nítorí pé, àwọn olórí ni wọ́n ṣiwaju ní Israẹli, àwọn eniyan sì fi tọkàntọkàn fa ara wọn kalẹ̀. Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọba; ẹ tẹ́tí sílẹ̀ ẹ̀yin ìjòyè; OLUWA ni n óo kọrin sí, n óo kọrin dídùn sí OLUWA, Ọlọrun Israẹli.

