ÀWỌN ADÁJỌ́ 14:14

ÀWỌN ADÁJỌ́ 14:14 YCE

Ó bá pa àlọ́ náà fún wọn, ó ní, “Láti inú ọ̀jẹun ni nǹkan jíjẹ tií wá, láti inú alágbára sì ni nǹkan dídùn tií wá.” Wọn kò sì lè túmọ̀ àlọ́ rẹ̀ fún ọjọ́ mẹta.