AISAYA 53:6

AISAYA 53:6 YCE

Gbogbo wa ti ṣáko lọ bí aguntan, olukuluku wa yà sí ọ̀nà tirẹ̀, OLUWA sì ti kó ẹ̀ṣẹ̀ gbogbo wa lé e lórí.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún AISAYA 53:6

AISAYA 53:6 - Gbogbo wa ti ṣáko lọ bí aguntan,
olukuluku wa yà sí ọ̀nà tirẹ̀,
OLUWA sì ti kó ẹ̀ṣẹ̀ gbogbo wa lé e lórí.