AISAYA 42:8-9

AISAYA 42:8-9 YCE

“Èmi ni OLUWA, bẹ́ẹ̀ ni orúkọ mi; n kò ní fi ògo mi fún ẹlòmíràn, n kò sì ní fi ìyìn mi fún ère. Wò ó! Àwọn nǹkan àtijọ́ ti kọjá, àwọn nǹkan tuntun ni mò ń kéde nisinsinyii. Kí wọn tó yọjú jáde rárá, ni mo ti sọ fún ọ nípa wọn.”