AISAYA 40:4

AISAYA 40:4 YCE

Gbogbo àfonífojì ni a óo ru sókè, a óo sì sọ àwọn òkè ńlá ati òkè kéékèèké di pẹ̀tẹ́lẹ̀: Gbogbo ọ̀nà tí ó wọ́ ni yóo di títọ́, ọ̀nà gbágun-gbàgun yóo sì di títẹ́jú.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún AISAYA 40:4

AISAYA 40:4 - Gbogbo àfonífojì ni a óo ru sókè,
a óo sì sọ àwọn òkè ńlá ati òkè kéékèèké di pẹ̀tẹ́lẹ̀:
Gbogbo ọ̀nà tí ó wọ́ ni yóo di títọ́,
ọ̀nà gbágun-gbàgun yóo sì di títẹ́jú.AISAYA 40:4 - Gbogbo àfonífojì ni a óo ru sókè,
a óo sì sọ àwọn òkè ńlá ati òkè kéékèèké di pẹ̀tẹ́lẹ̀:
Gbogbo ọ̀nà tí ó wọ́ ni yóo di títọ́,
ọ̀nà gbágun-gbàgun yóo sì di títẹ́jú.