AISAYA 40:31

AISAYA 40:31 YCE

Ṣugbọn àwọn tí ó bá dúró de OLUWA yóo máa gba agbára kún agbára. Wọn óo máa fi ìyẹ́ fò lọ sókè bí ẹyẹ idì. Wọn óo máa sáré, agara kò ní dá wọn; wọn óo máa rìn, kò sì ní rẹ̀ wọ́n.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún AISAYA 40:31

AISAYA 40:31 - Ṣugbọn àwọn tí ó bá dúró de OLUWA
yóo máa gba agbára kún agbára.
Wọn óo máa fi ìyẹ́ fò lọ sókè bí ẹyẹ idì.
Wọn óo máa sáré, agara kò ní dá wọn;
wọn óo máa rìn, kò sì ní rẹ̀ wọ́n.AISAYA 40:31 - Ṣugbọn àwọn tí ó bá dúró de OLUWA

wọn óo máa rìn, kò sì ní rẹ̀ wọ́n.