AISAYA 40:28

AISAYA 40:28 YCE

Ṣé o kò tíì mọ̀, o kò sì tíì gbọ́ pé Ọlọrun ayérayé ni OLUWA, Ẹlẹ́dàá gbogbo ayé. Kì í rẹ̀ ẹ́, bẹ́ẹ̀ ni agara kì í dá a. Àwámárìídìí ni òye rẹ̀.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún AISAYA 40:28

AISAYA 40:28 - Ṣé o kò tíì mọ̀,
o kò sì tíì gbọ́
pé Ọlọrun ayérayé ni OLUWA,
Ẹlẹ́dàá gbogbo ayé.
Kì í rẹ̀ ẹ́, bẹ́ẹ̀ ni agara kì í dá a.
Àwámárìídìí ni òye rẹ̀.AISAYA 40:28 - Ṣé o kò tíì mọ̀,
o kò sì tíì gbọ́
pé Ọlọrun ayérayé ni OLUWA,
Ẹlẹ́dàá gbogbo ayé.
Kì í rẹ̀ ẹ́, bẹ́ẹ̀ ni agara kì í dá a.
Àwámárìídìí ni òye rẹ̀.AISAYA 40:28 - Ṣé o kò tíì mọ̀,
o kò sì tíì gbọ́
pé Ọlọrun ayérayé ni OLUWA,
Ẹlẹ́dàá gbogbo ayé.
Kì í rẹ̀ ẹ́, bẹ́ẹ̀ ni agara kì í dá a.
Àwámárìídìí ni òye rẹ̀.