ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 3:4-5

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 3:4-5 YCE

Àkókò ẹkún wà, àkókò ẹ̀rín sì wà; àkókò ọ̀fọ̀ wà, àkókò ijó sì wà. Àkókò fífọ́n òkúta ká wà, àkókò kíkó òkúta jọ sì wà; àkókò ìkónimọ́ra wà, àkókò àìkónimọ́ra sì wà.