ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 1:7

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 1:7 YCE

Inú òkun ni gbogbo odò tí ń ṣàn ń lọ, ṣugbọn òkun kò kún. Ibi tí àwọn odò ti ń ṣàn wá, ibẹ̀ ni wọ́n tún ṣàn pada lọ.