ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 1:3-4

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 1:3-4 YCE

Èrè kí ni eniyan ń jẹ ninu gbogbo làálàá rẹ̀, tí ó ń ṣe nílé ayé? Ìran kan ń kọjá lọ, òmíràn ń dé, ṣugbọn ayé wà títí laelae.