ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 1:14

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 1:14 YCE

Mo ti wo gbogbo nǹkan tí eniyan ń ṣe láyé, wò ó, asán ati ìmúlẹ̀mófo ni gbogbo rẹ̀.