Ìran tí Amosi, ọ̀kan ninu àwọn darandaran Tekoa, rí nípa Israẹli nìyí, nígbà ayé Usaya, ọba Juda, ati Jeroboamu, ọmọ Jehoaṣi, ọba Israẹli, ní ọdún meji ṣáájú ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ṣẹlẹ̀ tí ilẹ̀ fi mì jìgìjìgì. Amosi ní: “OLUWA bú ramúramù lórí Òkè Sioni, ó fọhùn ní Jerusalẹmu; àwọn pápá tútù rọ, ewéko tútù orí òkè Kamẹli sì rẹ̀.”
Kà AMOSI 1
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: AMOSI 1:1-2
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò