ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 28:31

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 28:31 YCE

Ó ń waasu ìjọba Ọlọrun. Ó ń kọ́ àwọn eniyan nípa Oluwa Jesu Kristi láì bẹ̀rù ohunkohun. Ẹnikẹ́ni kò sì dí i lọ́wọ́.