ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 28:26-27

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 28:26-27 YCE

Ó ní, ‘Lọ sọ fún àwọn eniyan yìí pé: Ẹ óo fetí yín gbọ́, ṣugbọn kò ní ye yín; Ẹ óo wò ó títí, ṣugbọn ẹ kò ní mọ̀ ọ́n. Nítorí ọkàn àwọn eniyan yìí kò ṣí; wọ́n ti di alágbọ̀ọ́ya, wọ́n ti dijú. Bí kò bá ṣe bẹ́ẹ̀, wọn ìbá fi ojú wọn ríran, wọn ìbá fetí gbọ́ràn, òye ìbá yé wọn, wọn ìbá yipada; èmi ìbá sì wò wọ́n sàn.’