ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 2:46
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 2:46 YCE
Wọ́n ń fi ọkàn kan lọ sí Tẹmpili lojoojumọ. Wọ́n jọ ń jẹun láti ilé dé ilé. Wọ́n jọ ń jẹun pẹlu ayọ̀ ati pẹlu ọkàn kan.