ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 2:44

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 2:44 YCE

Gbogbo àwọn onigbagbọ wà ní ibìkan náà. Wọ́n jọ ní ohun gbogbo ní àpapọ̀.