TẸSALONIKA KEJI 1:5

TẸSALONIKA KEJI 1:5 YCE

Ìfaradà yín jẹ́ ẹ̀rí ìdájọ́ òdodo Ọlọrun láti kà yín yẹ fún ìjọba rẹ̀ tí ẹ̀ ń tìtorí rẹ̀ jìyà.