SAMUẸLI KEJI 12:15-16

SAMUẸLI KEJI 12:15-16 YCE

Natani bá lọ sí ilé rẹ̀. OLUWA fi àìsàn ṣe ọmọ tí aya Uraya bí fún Dafidi. Dafidi bá ń gbadura sí Ọlọrun pé kí ara ọmọ náà lè yá, ó ń gbààwẹ̀, ó sì ń sùn lórí ilẹ̀ lásán ní alaalẹ́.