ÀWỌN ỌBA KEJI 12:2

ÀWỌN ỌBA KEJI 12:2 YCE

Ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀ ó ṣe ohun tí ó tọ́ lójú OLUWA nítorí pé Jehoiada alufaa ń tọ́ ọ sọ́nà.