ÀWỌN ỌBA KINNI 3:8

ÀWỌN ỌBA KINNI 3:8 YCE

O sì fi èmi iranṣẹ rẹ sí ààrin àwọn eniyan tí o ti yàn fún ara rẹ, àwọn tí wọ́n pọ̀, tóbẹ́ẹ̀ tí wọn kò lóǹkà.