1
Saamu 50:14-15
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
“Rú ẹbọ ọpẹ́ sí Ọlọ́run, kí o sì san ẹ̀jẹ́ rẹ fún Ọ̀gá-ògo. Kí o sì pè mí ní ọjọ́ ìpọ́njú, èmi yóò gbà ọ́, ìwọ yóò sì bu ọlá fún mi.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 50:14-15
2
Saamu 50:10-11
nítorí gbogbo ẹran igbó ni tèmi àti ẹran ọ̀sìn lórí ẹgbẹ̀rún (1,000) òkè. Èmi mọ gbogbo ẹyẹ ní orí àwọn òkè ńlá àti gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ó wà ní orí ilẹ̀ ni tèmi.
Ṣàwárí Saamu 50:10-11
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò