Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 28

1

Saamu 28:7

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA ni agbára mi àti asà mi; nínú rẹ̀ ni mo gbẹ́kẹ̀lé; àní, ó sì ràn mí lọ́wọ́. Ọkàn mi sì gbé sókè fún ayọ̀ àní pẹ̀lú orin mi mo fi ọpẹ́ fún un.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 28:7

2

Saamu 28:8

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA ni agbára àwọn ènìyàn rẹ̀ òun ni odi ìgbàlà àwọn ẹni àmì òróró rẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 28:8

3

Saamu 28:6

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Alábùkún fún ni OLúWA! Nítorí pé ó ti gbọ́ ohùn ẹ̀bẹ̀ mi.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 28:6

4

Saamu 28:9

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ìwọ gba àwọn ènìyàn rẹ là, kí o sì bùkún àwọn ajogún rẹ; di olùṣọ́-àgùntàn wọn, kí o sì gbé wọn lékè títí ayérayé.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 28:9

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 28

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest