Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 27

1

Saamu 27:14

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Dúró de OLúWA; kí ó jẹ alágbára, kí o sì mú ọkàn le àní dúró de OLúWA.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 27:14

2

Saamu 27:4

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ohun kan ni mo béèrè lọ́dọ̀ OLúWA, òhun ni èmi yóò máa wá kiri: kí èmi kí ó le wà ní ilé OLúWA ní ọjọ́ ayé mi gbogbo, kí èmi: kí ó le kíyèsi ẹwà OLúWA, kí èmi kí ó sì máa wà ní tẹmpili rẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 27:4

3

Saamu 27:1

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA ni ìmọ́lẹ̀ mi àti ìgbàlà mi; ta ni èmi yóò bẹ̀rù? OLúWA ni ibi ìsádi ẹ̀mí mi, ẹ̀rù ta ni yóò bà mí?

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 27:1

4

Saamu 27:13

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Èmi ní ìgbàgbọ́ pé, èmi yóò rí ìre OLúWA ní ilẹ̀ alààyè.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 27:13

5

Saamu 27:5

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nítorí pé ní ìgbà ìpọ́njú òun yóò pa mí mọ́ nínú àgọ́ rẹ̀; níbi ìkọ̀kọ̀ àgọ́ rẹ̀ ni òun yóò pa mí mọ́; yóò sì gbé mi sókè lórí àpáta.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 27:5

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 27

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest