Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 100

1

Saamu 100:5

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nítorí tí OLúWA pọ̀ ní oore ìfẹ́ rẹ̀ sì wà títí láé; àti òtítọ́ rẹ̀ láti ìran de ìran.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 100:5

2

Saamu 100:4

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ẹ lọ sí ẹnu-ọ̀nà rẹ̀ pẹ̀lú ọpẹ́ àti sí àgbàlá rẹ̀ pẹ̀lú ìyìn; ẹ fi ọpẹ́ àti ìyìn fún orúkọ rẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 100:4

3

Saamu 100:2

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ẹ fi ayọ̀ sin OLúWA, ẹ wá síwájú rẹ̀ pẹ̀lú orin dídùn

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 100:2

4

Saamu 100:3

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA Ọlọ́run ni ó dá wa, kí ẹ̀yin kí ó mọ̀ pé tirẹ̀ ni àwa, àwa ní ènìyàn rẹ̀ àti àgùntàn pápá rẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 100:3

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest