O. Daf 100:5
O. Daf 100:5 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori ti Oluwa pọ̀ li ore; ãnu rẹ̀ kò nipẹkun; ati otitọ rẹ̀ lati iran-diran.
O. Daf 100:5 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí OLUWA ṣeun; ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae, òtítọ́ rẹ̀ sì wà láti ìran dé ìran.