1
Òwe 7:2-3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Pa òfin mi mọ́, ìwọ yóò sì yè tọ́jú ẹ̀kọ́ mi bí ẹyinlójú rẹ. Kọ wọ́n sí ọwọ́ òsì rẹ, má ṣe fi jẹun kọ wọ́n sí inú wàláà àyà rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Òwe 7:2-3
2
Òwe 7:1
Ọmọ mi, pa ọ̀rọ̀ mi mọ́, sì fi àwọn òfin mi pamọ́ sínú ọkàn rẹ.
Ṣàwárí Òwe 7:1
3
Òwe 7:5
Wọn yóò pa ó mọ́ kúrò lọ́wọ́ obìnrin alágbèrè, kúrò lọ́wọ́ àjèjì obìnrin àti ọ̀rọ̀ ìtànjẹ rẹ̀.
Ṣàwárí Òwe 7:5
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò