1
Ìṣe àwọn Aposteli 27:25
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Ǹjẹ́ nítorí náà, alàgbà, ẹ dárayá: nítorí mo gba Ọlọ́run gbọ́ pé, yóò rí bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ bí a ti sọ fún mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 27:25
2
Ìṣe àwọn Aposteli 27:23-24
Nítorí angẹli Ọlọ́run, ẹni tí èmi jẹ́ tirẹ̀, àti ẹni ti èmi ń sìn, ó dúró tì mi ni òru àná. Ó wí pé, ‘Má bẹ̀rù, Paulu; ìwọ kò lè ṣàìmá dúró níwájú Kesari. Sì wò ó, Ọlọ́run ti fi gbogbo àwọn ti ó bá ọ wọ ọkọ̀ pọ̀ fún ọ.’
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 27:23-24
3
Ìṣe àwọn Aposteli 27:22
Ǹjẹ́ nísinsin yìí mó gbà yín níyànjú, kí ẹ tújúká; nítorí kí yóò sí òfò ẹ̀mí nínú yín, bí kò ṣe ti ọkọ̀.
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 27:22
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò