Iṣe Apo 27:25
Iṣe Apo 27:25 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí náà ẹ̀yin eniyan, ẹ ṣara gírí, nítorí mo gba Ọlọrun gbọ́ pé bí ó ti sọ fún mi ni yóo rí.
Iṣe Apo 27:25 Bibeli Mimọ (YBCV)
Njẹ nitorina, alàgba, ẹ daraya: nitori mo gbà Ọlọrun gbọ́ pe, yio ri bẹ̃ gẹgẹ bi a ti sọ fun mi.