Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ 2 Samuẹli 22

1

2 Samuẹli 22:3

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ọlọ́run mi, àpáta mi, nínú ẹni tí èmi ní ààbò, àti ìwo ìgbàlà mi, ibi ìsádi gíga mi. Àti ibi ìlùmọ̀ mi, Olùgbàlà mi; ìwọ ni ó ti gbà mí kúrò lọ́wọ́ ìwà ipá.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí 2 Samuẹli 22:3

2

2 Samuẹli 22:31

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

“Ọlọ́run yìí, pípé ni ọ̀nà rẹ̀; ọ̀rọ̀ OLúWA ni a ti dánwò. Òun sì ni asà fún gbogbo àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé e.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí 2 Samuẹli 22:31

3

2 Samuẹli 22:2

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ó sì wí pé, “OLúWA ni àpáta mi, àti Olùgbàlà mi

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí 2 Samuẹli 22:2

4

2 Samuẹli 22:33

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ọlọ́run alágbára ni ó fún mi ní agbára, ó sì sọ ọ̀nà mi di títọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí 2 Samuẹli 22:33

5

2 Samuẹli 22:29

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Nítorí ìwọ ni ìmọ́lẹ̀ mi, OLúWA; OLúWA yóò sì sọ òkùnkùn mi di ìmọ́lẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí 2 Samuẹli 22:29

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò