1
O. Daf 112:7
Bibeli Mimọ
YBCV
Kì yio bẹ̀ru ihin buburu: aiya rẹ̀ ti mu ọ̀na kan, o gbẹkẹle Oluwa.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 112:7
2
O. Daf 112:1-2
Ẹ ma yìn Oluwa. Ibukún ni fun ẹniti o bẹ̀ru Oluwa, ti inu rẹ̀ dùn jọjọ sí ofin rẹ̀. Iru-ọmọ rẹ̀ yio lagbara li aiye: iran ẹni-diduro-ṣinṣin li a o bukún fun.
Ṣàwárí O. Daf 112:1-2
3
O. Daf 112:8
Aiya rẹ̀ ti mulẹ, kì yio bẹ̀ru, titi yio fi ri ifẹ rẹ̀ lori awọn ọta rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 112:8
4
O. Daf 112:4
Fun ẹni-diduro-ṣinṣin ni imọlẹ mọ́ li òkunkun: olore-ọfẹ, o si kún fun ãnu, o si ṣe olododo.
Ṣàwárí O. Daf 112:4
5
O. Daf 112:5
Enia rere fi oju-rere hàn, a si wínni: imoye ni yio ma fi là ọ̀na iṣẹ rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 112:5
6
O. Daf 112:6
Nitoriti a kì yio yi i nipò pada lailai: olododo yio wà ni iranti titi aiye.
Ṣàwárí O. Daf 112:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò