O. Daf 112:4
O. Daf 112:4 Yoruba Bible (YCE)
Ìmọ́lẹ̀ yóo tàn fún olódodo ninu òkùnkùn, olóore ọ̀fẹ́ ni OLUWA, aláàánú ni, a sì máa ṣòdodo.
O. Daf 112:4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Fun ẹni-diduro-ṣinṣin ni imọlẹ mọ́ li òkunkun: olore-ọfẹ, o si kún fun ãnu, o si ṣe olododo.