Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 140

1

ORIN DAFIDI 140:13

Yoruba Bible

YCE

Dájúdájú, àwọn olódodo yóo máa fi ọpẹ́ fún ọ; àwọn olóòótọ́ yóo sì máa gbé níwájú rẹ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 140:13

2

ORIN DAFIDI 140:1-2

Yoruba Bible

YCE

OLUWA, gbà mí lọ́wọ́ àwọn ẹni ibi; dáàbò bò mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá; àwọn tí ó ń pète ibi lọ́kàn wọn, tí wọ́n sì ń dá ogun sílẹ̀ nígbàkúùgbà

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 140:1-2

3

ORIN DAFIDI 140:12

Yoruba Bible

YCE

Mo mọ̀ pé OLUWA yóo gba ọ̀ràn olùpọ́njú rò, yóo sì ṣe ìdájọ́ òdodo fún àwọn aláìní.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 140:12

4

ORIN DAFIDI 140:4

Yoruba Bible

YCE

OLUWA, ṣọ́ mi lọ́wọ́ àwọn eniyan burúkú; dáàbò bò mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá, tí ó ń gbìmọ̀ láti ré mi lẹ́pa.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 140:4

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò