O. Daf 140:1-2
O. Daf 140:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
OLúWA, gbà mi lọ́wọ́ ọkùnrin búburú u nì, yọ mí lọ́wọ́ ọkùnrin ìkà a nì; Ẹni tí ń ro ìwà búburú ní inú wọn; nígbà gbogbo ni wọ́n ń rú ìjà sókè sí mi.
O. Daf 140:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
OLUWA gbà mi lọwọ ọkunrin buburu nì, yọ mi lọwọ ọkunrin ìka nì; Ẹniti nrò ìwa-buburu ni inu wọn; nigbagbogbo ni nwọn nrú ìja soke si mi.
O. Daf 140:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
OLUWA gbà mi lọwọ ọkunrin buburu nì, yọ mi lọwọ ọkunrin ìka nì; Ẹniti nrò ìwa-buburu ni inu wọn; nigbagbogbo ni nwọn nrú ìja soke si mi.