1
ORIN DAFIDI 125:1
Yoruba Bible
YCE
Àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé OLUWA dàbí òkè Sioni, tí ẹnikẹ́ni kò lè ṣí nídìí, ṣugbọn tí ó wà títí lae.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 125:1
2
ORIN DAFIDI 125:2
Bí òkè ńlá ti yí Jerusalẹmu ká, bẹ́ẹ̀ ni OLUWA yí àwọn eniyan rẹ̀ ká, láti ìsinsìnyìí lọ ati títí lae.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 125:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò