Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ JOBU 17

1

JOBU 17:9

Yoruba Bible

YCE

Sibẹsibẹ olódodo kò fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀, ẹni tí ọwọ́ rẹ̀ mọ́ sì ń lágbára sí i.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí JOBU 17:9

2

JOBU 17:3

Yoruba Bible

YCE

Fi nǹkan ẹ̀jẹ́ kan lélẹ̀ fún mi lọ́dọ̀ rẹ; ta ló wà níbẹ̀ tí yóo ṣe onídùúró fún mi?

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí JOBU 17:3

3

JOBU 17:1

Yoruba Bible

YCE

“Ọkàn mi bàjẹ́, ọjọ́ ayé mi ti dópin, ibojì sì ń dúró dè mí.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí JOBU 17:1

4

JOBU 17:11-12

Yoruba Bible

YCE

“Ọjọ́ ayé mi ti dópin, èrò ọkàn mi ti dàrú, àwọn ohun tí ọkàn mi ń fẹ́ sì ti di asán. Wọ́n sọ òru di ọ̀sán, wọ́n ń sọ pé, ‘Ìmọ́lẹ̀ kò jìnnà sí òkùnkùn.’

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí JOBU 17:11-12

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò