1
JEREMAYA 33:3
Yoruba Bible
YCE
“Ẹ ké pè mí, n óo sì da yín lóhùn; n óo sọ nǹkan ìjìnlẹ̀ ati ìyanu ńlá, tí ẹ kò mọ̀ tẹ́lẹ̀ fun yín.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JEREMAYA 33:3
2
JEREMAYA 33:6-7
N óo mú ìlera ati ìwòsàn wá bá wọn; n óo wò wọ́n sàn, n óo sì fún wọn ní ọpọlọpọ ibukun ati ìfọ̀kànbalẹ̀. N óo dá ire Juda ati ti Israẹli pada, n óo sì tún wọn kọ́, wọn yóo dàbí wọ́n ti rí lákọ̀ọ́kọ́.
Ṣàwárí JEREMAYA 33:6-7
3
JEREMAYA 33:8
N óo wẹ̀ wọ́n mọ́ kúrò ninu gbogbo ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n dá sí mi, n óo dárí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ ati oríkunkun tí wọ́n ṣe sí mi jì wọ́n.
Ṣàwárí JEREMAYA 33:8
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò