Jer 33:3
Jer 33:3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Képe mi, emi o si da ọ lohùn, emi o si fi ohun nla ati alagbara han ọ ti iwọ kò mọ̀.
Pín
Kà Jer 33Jer 33:3 Yoruba Bible (YCE)
“Ẹ ké pè mí, n óo sì da yín lóhùn; n óo sọ nǹkan ìjìnlẹ̀ ati ìyanu ńlá, tí ẹ kò mọ̀ tẹ́lẹ̀ fun yín.”
Pín
Kà Jer 33