1
JEREMAYA 16:21
Yoruba Bible
YCE
OLUWA ní, “Nítorí náà, wò ó, n óo jẹ́ kí wọn mọ̀; àní sẹ́, n óo jẹ́ kí wọ́n mọ agbára ati ipá mi; wọn yóo sì mọ̀ pé orúkọ mi ni OLUWA.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JEREMAYA 16:21
2
JEREMAYA 16:19
OLUWA, ìwọ ni agbára mi, ati ibi ààbò mi, ìwọ ni ibi ìsápamọ́sí mi, ní ìgbà ìpọ́njú. Àwọn orílẹ̀-èdè yóo wá sọ́dọ̀ rẹ, láti gbogbo òpin ayé, wọn yóo máa wí pé: “Irọ́ patapata ni àwọn baba wa jogún, ère lásánlàsàn tí kò ní èrè kankan.
Ṣàwárí JEREMAYA 16:19
3
JEREMAYA 16:20
Ṣé eniyan lè fi ọwọ́ ara rẹ̀ ṣẹ̀dá ọlọrun? Irú ọlọrun bẹ́ẹ̀ kì í ṣe ọlọrun rárá.”
Ṣàwárí JEREMAYA 16:20
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò