1
SAMUẸLI KEJI 9:7
Yoruba Bible
YCE
Dafidi wí fún un pé, “Má bẹ̀rù, oore ni mo fẹ́ ṣe ọ́ nítorí Jonatani baba rẹ. Gbogbo ilẹ̀ tí ó ti jẹ́ ti Saulu baba baba rẹ rí, ni n óo dá pada fún ọ, a óo sì jọ máa jẹun lórí tabili mi nígbà gbogbo.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 9:7
2
SAMUẸLI KEJI 9:1
Ní ọjọ́ kan, Dafidi bèèrè pé, “Ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni kù ninu gbogbo ìdílé Saulu tí mo lè ṣoore fún nítorí Jonatani?”
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 9:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò