II. Sam 9:1
II. Sam 9:1 Yoruba Bible (YCE)
Ní ọjọ́ kan, Dafidi bèèrè pé, “Ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni kù ninu gbogbo ìdílé Saulu tí mo lè ṣoore fún nítorí Jonatani?”
Pín
Kà II. Sam 9II. Sam 9:1 Bibeli Mimọ (YBCV)
DAFIDI si bere pe, ọkan ninu awọn ẹniti iṣe idile Saulu kù sibẹ bi? ki emi ki o le ṣe ore fun u nitori Jonatani.
Pín
Kà II. Sam 9