Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní

25 Oṣù Owewe 2025

Johanu 14:6 - Jesu dá wọn lóhùn pé, “Èmi ni ọ̀nà, òtítọ́ àti ìyè: kò sí ẹnikẹ́ni tí ó lè wá sọ́dọ̀ Baba, bí kò ṣe nípasẹ̀ mi.
Pín
Johanu 14:6 - Jesu dá wọn lóhùn pé, “Èmi ni ọ̀nà, òtítọ́ àti ìyè: kò sí ẹnikẹ́ni tí ó lè wá sọ́dọ̀ Baba, bí kò ṣe nípasẹ̀ mi.
Pín
Johanu 14:6 - Jesu dá wọn lóhùn pé, “Èmi ni ọ̀nà, òtítọ́ àti ìyè: kò sí ẹnikẹ́ni tí ó lè wá sọ́dọ̀ Baba, bí kò ṣe nípasẹ̀ mi.
Pín
Èyí tó kànÈyí tó kàn
Jesu dá wọn lóhùn pé, “Èmi ni ọ̀nà, òtítọ́ àti ìyè: kò sí ẹnikẹ́ni tí ó lè wá sọ́dọ̀ Baba, bí kò ṣe nípasẹ̀ mi.

Johanu 14:6 (YCB)

Kà Johanu 14:6
Fọwọ́ síi

Àwon ètò Bíbélì

Bẹ̀rẹ̀ sí í ka ẹsẹ Bíbélì kan lójoojúmọ́

Rírìn Ní Ọ̀nà Náà

Rírìn Ní Ọ̀nà Náà

Ọjọ́ Márùn-ún

Wíwàásù Jesu Pẹ̀lú Ìgboyà

Wíwàásù Jesu Pẹ̀lú Ìgboyà

5 Awọn ọjọ

Aláìjuwọ́sílẹ̀ Pèlú Lisa Bevere

Aláìjuwọ́sílẹ̀ Pèlú Lisa Bevere

Ọjọ́ mẹ́fà

Bẹrẹ Ọrẹ Kan Pẹlu Jesu

Bẹrẹ Ọrẹ Kan Pẹlu Jesu

Ọjọ́ méje

Àlàáfíà tó Sonù

Àlàáfíà tó Sonù

Ọjọ́ Méje

Bíbélì Wà Láàyè

Bíbélì Wà Láàyè

Ọjọ́ Méje

Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù Èmí

Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù Èmí

Ọgbọ̀n ọjọ́

Àwọn ẹsẹ Bíbélì tó wà fún ọ̀sẹ̀ yìí

24 Oṣù Owewe 2025

Ta ni ó gbọ́n tí ó sì ní ìmọ̀ nínú yín? Ẹ jẹ́ kí ó fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn nípa ìwà rere, nípa ìwà tútù ti ọgbọ́n.

Jakọbu 3:13 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 24 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 0

23 Oṣù Owewe 2025

Nítorí nípa rẹ̀ ni àwa méjèèjì ti ni àǹfààní sọ́dọ̀ baba nípa Ẹ̀mí kan.

Efesu 2:18 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 23 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 1

22 Oṣù Owewe 2025

“Jesu sì wí fún un pé, ‘Bí ìwọ bá le gbàgbọ́: ohun gbogbo ni ó ṣe é ṣe fún ẹni tí ó bá gbàgbọ́.’ ”

Marku 9:23 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 22 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 2

21 Oṣù Owewe 2025

“Ẹni tí ó bá ṣe olóòtítọ́ nínú ohun kínkínní, ó ṣe olóòtítọ́ ní púpọ̀ pẹ̀lú: ẹni tí ó bá sì ṣe aláìṣòótọ́ ní ohun kínkínní, ó ṣe aláìṣòótọ́ ní ohun púpọ̀ pẹ̀lú.

Luku 16:10 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 21 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 3

20 Oṣù Owewe 2025

Nínú ìbáṣepọ̀ yin pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn, ẹ ni irú ìlépa ọkàn náà bí ti Kristi Jesu.

Filipi 2:5 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 20 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 4

19 Oṣù Owewe 2025

Nítorí náà, Ẹ lọ, ẹ sọ wọ́n di ọmọ-ẹ̀yìn orílẹ̀-èdè gbogbo, ẹ máa bamitiisi wọn ní orúkọ Baba àti ti Ọmọ àti ti Ẹ̀mí Mímọ́.

Matiu 28:19 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 19 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 5
Ṣe Ìgbàsílẹ̀ Ohun Èlò náà

Gba Bíbélì ọ̀fẹ́ ti orí ayélujára fún fóònù àti tábúlẹ̀tì.

Gbá ohun èlò ti Bíbélì ìsisìyíwàyí
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò