Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní

24 Oṣù Owewe 2025

Jakọbu 3:13 - Ta ni ó gbọ́n tí ó sì ní ìmọ̀ nínú yín? Ẹ jẹ́ kí ó fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn nípa ìwà rere, nípa ìwà tútù ti ọgbọ́n.
Pín
Jakọbu 3:13 - Ta ni ó gbọ́n tí ó sì ní ìmọ̀ nínú yín? Ẹ jẹ́ kí ó fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn nípa ìwà rere, nípa ìwà tútù ti ọgbọ́n.
Pín
Èyí tó kànÈyí tó kàn
Ta ni ó gbọ́n tí ó sì ní ìmọ̀ nínú yín? Ẹ jẹ́ kí ó fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn nípa ìwà rere, nípa ìwà tútù ti ọgbọ́n.

Jakọbu 3:13 (YCB)

Kà Jakọbu 3:13
Fọwọ́ síi

Àwọn ẹsẹ Bíbélì tó wà fún ọ̀sẹ̀ yìí

23 Oṣù Owewe 2025

Nítorí nípa rẹ̀ ni àwa méjèèjì ti ni àǹfààní sọ́dọ̀ baba nípa Ẹ̀mí kan.

Efesu 2:18 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 23 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 0

22 Oṣù Owewe 2025

“Jesu sì wí fún un pé, ‘Bí ìwọ bá le gbàgbọ́: ohun gbogbo ni ó ṣe é ṣe fún ẹni tí ó bá gbàgbọ́.’ ”

Marku 9:23 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 22 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 1

21 Oṣù Owewe 2025

“Ẹni tí ó bá ṣe olóòtítọ́ nínú ohun kínkínní, ó ṣe olóòtítọ́ ní púpọ̀ pẹ̀lú: ẹni tí ó bá sì ṣe aláìṣòótọ́ ní ohun kínkínní, ó ṣe aláìṣòótọ́ ní ohun púpọ̀ pẹ̀lú.

Luku 16:10 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 21 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 2

20 Oṣù Owewe 2025

Nínú ìbáṣepọ̀ yin pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn, ẹ ni irú ìlépa ọkàn náà bí ti Kristi Jesu.

Filipi 2:5 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 20 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 3

19 Oṣù Owewe 2025

Nítorí náà, Ẹ lọ, ẹ sọ wọ́n di ọmọ-ẹ̀yìn orílẹ̀-èdè gbogbo, ẹ máa bamitiisi wọn ní orúkọ Baba àti ti Ọmọ àti ti Ẹ̀mí Mímọ́.

Matiu 28:19 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 19 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 4

18 Oṣù Owewe 2025

Kò le sí Júù tàbí Giriki, ẹrú tàbí òmìnira, ọkùnrin tàbí obìnrin nítorí pé ọ̀kan ni nínú Kristi Jesu.

Galatia 3:28 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 18 Oṣù Owewe 2025 - àwòrán 5
Ṣe Ìgbàsílẹ̀ Ohun Èlò náà

Gba Bíbélì ọ̀fẹ́ ti orí ayélujára fún fóònù àti tábúlẹ̀tì.

Gbá ohun èlò ti Bíbélì ìsisìyíwàyí
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò