Rom 11:33-36

Ã! ijinlẹ ọrọ̀ ati ọgbọ́n ati ìmọ Ọlọrun! awamáridi idajọ rẹ̀ ti ri, ọ̀na rẹ̀ si jù awari lọ! Nitori tali o mọ̀ inu Oluwa? tabi tani iṣe ìgbimọ rẹ̀? Tabi tali o kọ́ fifun u, ti a o si san a pada fun u? Nitori lati ọdọ rẹ̀, ati nipa rẹ̀, ati fun u li ohun gbogbo: ẹniti ogo wà fun lailai. Amin.
Rom 11:33-36