Ọrọ̀ ọlọrọ̀ ni ilu-agbara rẹ̀, o si dabi odi giga li oju ara rẹ̀. Ṣaju iparun, aiya enia a ṣe agidi, ṣaju ọlá si ni irẹlẹ.
Owe 18:11-12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò