Jesu wi fun u pe, Iwọ ti ri i, on na si ni ẹniti mba ọ sọ̀rọ yi. O si wipe, Oluwa, mo gbagbọ́, o si wolẹ fun u. Jesu si wipe, Nitori idajọ ni mo ṣe wá si aiye yi, ki awọn ti kò riran, le riran; ati ki awọn ti o riran le di afọju.
Joh 9:37-39
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò