Baba fẹ Ọmọ, o si ti fi ohun gbogbo le e lọwọ. Ẹniti o ba gbà Ọmọ gbọ́, o ni iye ainipẹkun: ẹniti kò ba si gbà Ọmọ gbọ, kì yio ri ìye; ṣugbọn ibinu Ọlọrun mbẹ lori rẹ̀.
Joh 3:35-36
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò