Àwọn èsì àwárí fún: 1 Samuel 7:13

I. Sam 7:13 (YBCV)

Bẹ̃li a tẹ ori awọn Filistini ba, nwọn kò si tun wá si agbegbe Israeli mọ: ọwọ́ Oluwa si wà ni ibi si awọn Filistini, ni gbogbo ọjọ Samueli.