Ohun Èlò Bíbélì jẹ ọfẹ pátápátá, laisi ìpolówó àti àwọn rírà ni-app. Gba ohun èlò
Mo Yọ̀ǹda: Ìwé-Ìfọkànsìn Asínilórì Láti Ọwọ́ Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n

Ọjọ́ 4
Bíbelì jẹ́ ìwé ìràpadà, òmìnira, àti ìrètí. Nínú àwọn ojú-ìwé rẹ̀ ni orírúirú ẹ̀dá ènìyàn, akínkanjú—àwọn oníròbìnùjẹ́-ọkàn l'ọ́kùnrin l'óbìnrin tí wọn ń wá ọ̀nà àbáyọ. Ní ọ̀nà kan tàbí òmínràn, wọ́n dàbìi àwọn àbọ̀dé elẹ́wọ̀n àná tàbí àwọn tí wọ́n ń ṣe ẹ̀wọ̀n lọ́wọ́lọ́wọ́ tí wọ́n kọ àwọn ìwé-ìfọkànsìn tí o fẹ́ kà báyìí. A ní èrò pé àwọn ohùn ìjọ làti inú àhámọ́ yìí yíó jẹ́ ìgbaniníyànjú àti ìwúrí fún ọ. Kí ọ̀rọ̀ ẹ̀rí wọn dá àwa náà s'ílẹ̀.
A fẹ́ láti dúpẹ́ lọ́wọ́ Prison Fellowship fún ìpèsè ètò yìí. Fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé, jọ̀wọ́ kàn sí: https://www.prisonfellowship.org/resources/subscribe
Àwọn Ètò tó Jẹmọ́ọ

Àlàáfíà Olórun

Ọlọ́run jẹ́_______

Títẹ̀lé Jésù Olùgbèjà Wa

Ẹnití a Yàn: Rán Ara Rẹ Létí Ìhìnrere Lójoojúmọ́

Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù Èmí

Wíwá Ọkàn Ọlọ́run Lójoojúmọ́ - Ọgbọ́n

Ìjọba Dé

Jesu fẹràn mi

Bí A Ti Lè Bẹ̀rẹ̀ Sí Ní Ka Bíbélì
