Aò Tíì Kọ̀ọ́sílẹ̀: Wíwá Òmìnira Gẹ́gẹ́ bíi Ọmọ Bàbá T'ópé

Ọjọ́ 5
Louie Giglio, Oluṣọ àgùntàn àti Olùdásílẹ̀ Passion Movement, kọ́ni láti inú ètò Ọlọjọ márùn yìí, nípa bí a ti ń lóye ìwà Ọlọ́run ní ònà tí yíó yí ayé wa padà - gẹgẹ bíi Bàbá tí ópé, ti o sì fẹ́ kí o rìn nínú òmìnira bíi ọmọ rẹ tí o féràn l'ọkunrin tàbí lóbìnrin.
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ẹgbẹ́ ẹ Lifeway Christian Resources fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí: https://notforsakenbook.com/
Díẹ̀ sí i láti ọwọ́ Louie Giglio