Àdúrà YouVersion

Ètò-ìṣiṣẹ́ Àdúrà Ojoojúmọ́

Ọ̀rọ̀ tọkàntọkàn pẹ̀lú Ọlọ́run, láwùjọ.

Ṣé ẹ fẹ́ bá Ọlọ́run sọ̀rọ̀, ṣùgbọ́n ẹ ò mọ ohun tí ẹ lè sọ? Àdúrà Ìtọni lè kọ́ yín bí ẹ ṣe lè gbàdúrà, á sì darí yín ní ṣíṣẹ̀-n-tẹ̀lé nípasẹ̀ àdúrà tó tẹ̀lé àpẹẹrẹ Àdúrà Olúwa.

Àdúrà YouVersion

Ṣàfikún àdúrà sí àtòkọ àdúrà yín.

Àdúrà YouVersion

Ẹ fi àwọn àdúrà yín pamọ́, tàbí kí ẹ pe àwọn ọ̀rẹ́ láti gbàdúrà pẹ̀lú yín.

Àdúrà YouVersion

Ẹ ṣètò ìránnilétí láti gbàdúrà, kí ẹ sì jẹ́ kí ètò-ìṣiṣẹ́ bá yín dàṣà àdúrà.

Àdúrà YouVersion

YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa